Agan, were, alaarun ni won n pe ‘ra won (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won)
Omugo, didinrin ni won n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won)
Alayebaje, atoole n’on n pe ‘ra won (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won)
Aletilapa ni won n p’omo won (oruko t’on n pe ‘ra won)
Ah e o mo p’ohun t’a ba pe loruko o lagbara lori eda
Ohun ti o n la koja ooo, jowo ma fi pe ‘ra e mo
Enikeni to ni ‘dojuko isese kan, e ma fi pe loruko
Ma f’epe san epe, maa ko oruko buburu, satani lo n je baun
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
A ti d’ele aye na, dandan ni k’a laagun k’a to yo, sise pelu ero ire, wa a yo
Awon elomiran a ni nile awon bi won o logun odun ni’gbeyawo won o ni le bimo
Won a ni nile won (won kii le ko’le)
Won a ni nile awon (won kii gbo k’on to ku)
Idojuko won (n’on fi n pe ‘ra won)
A ni aisan to n se ohun (n lo pa ‘ya ohun)
Won a tun fun loruko (alaarun idile)
Won a lohun gangan (logun ebi won)
Eda n f’oruko isoro (p’oriki ara re)
Won a ni b’o ti n se won (n’ile awon niyen)
Eda e so’ro to dara jade, ero alaafia lOlorun ni si wa
Ma f’ogun enu se ‘ra e pa
Pe ‘ra e ni hun to fe je
Oruko to dara lOlorun so mi
Oruko to logo o lEleda n pe mi
Oruko to dara ni emi n je
Aseda mo mi ire
Emi ako’rewaye
Emi agb’ayesayo
Mi o ya’gan lona kankan
Aisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Igbagbo n se pupo loro eda (alaisan ti o ni ‘gbagbo ko le gba ‘wosan)
Ireti logun f’oruko tuntun (alainireti ko le kuro loju kan)
Eda segun nipa oro enu re (iku ati iye wa lori ahon)
Ma s’ahon d’ida fi sa ara e si wewe (wa a jere ohun to ba f’enu so)
Eni to da’na s’aaro ti o gbe ‘hun le’na (o daju ko ni ‘hun se)
O kan fe ya’na lasan ni, igbagbo ni yo ba ero e sise
Ja ijangbara fun oruko rere, oruko lo n ro ni
Oruko to dara l’Olorun so mi
Oruko to logo o l’Eleda n pe mi
Oruko to dara ni emi n je
Aseda mo mi ire
Emi ako’rewaye
Emi agb’ayesayo
Mi o ya’gan lona kankan
Aisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Eda to n gbe ‘nu aye, yara pada s’odo Aseda
On lo mo’di oro, On lo le yanju e
F’Adaniwaye se edidi aye re, mura lati s’atunse gbogbo
Ko lati je oruko t’aye n so ni, to n ba ayanmo wo ‘jakadi
Ore b’Olorun d’owo po o, k’aye e ko le toro
Ore b’Olorun laja, ko le j’oruko tuntun
Oruko to dara lOlorun so mi
Oruko to logo o lEleda n pe mi
Oruko to dara ni emi n je
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Aseda mo mi ire
Emi ako’rewaye
Emi agb’ayesayo
Mi o ya’gan lona kankan
Aisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Obedi-Edomu j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun)
Bartholomew j’oruko tuntun (o je oruko tuntun)
Jakobu j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun)
Dafidi j’oruko tuntun (o je oruko tuntun)
Maria Magdaleni j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun)
Soolu j’oruko tuntun (o je oruko tuntun)
Peteru apeja j’oruko tuntun ooo (o j’oruko tuntun)
At’emi nipa eje odo aguntan, mo gba ire, to je ini mi pada
Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko
Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han
Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Emi t’a da (Emi t’a da)
Laworan Olorun (Olorun)
Emi eda (Emi eda)
Mo ri ojurere (Ojurere)
Mo loore ofe to ga julo
Emi lori (Emi lori)
Mi kii se iru o (Lailai)
Emi t’a da (Emi t’a da)
T’ewa t’ogo Olorun (Olorun)
Lat’odo Aseda o, ola mi o lakawe
A ti fi oruko tuntun pe mi, emi
A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin
A ti fi oruko tuntun pe mi, emi
A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin
A ti fi oruko tuntun pe mi, emi
A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin .