Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
MP3: Tope Alabi – Oruko Tuntun
Nigerian Gospel Artist Tope Alabi comes through with a new song in 2023 titled ‘Oruko Tuntun’ and it’s right here for your free mp3 download.
ALSO, READ Mike Abdul Ft Nosa – Keep It To Myself || Download Mp3 (Audio)
DOWNLOAD MP3: Tope Alabi – Oruko Tuntun BELOW
DOWNLOAD MP3
Lyrics Of ‘Oruko Tuntun’ By Tope Alabi
Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyanOlorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyanEto Olorun ni emi je
Aseda f’inu f’edo f’ife da mi
O mo mi ni iri Ohun gangan Mi o ku si’bi kan, O da mi daradara Emi lamo t’owo Adaniwaye mo
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Eemi Aseda ni iwalaaye mi
Oju ogo Re ni iriiran mi akoko Ipa lo fi se mi s’inu iya mi Ara nla owo Oga ogo ni mi Emi leniyanOlorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Irin ajo eda wa s’aye, esu, ota, elenini eniyan n duro
Ami ibi to tele eda bo ni satani t’a le sokale lat’orun O n bu ramuramu, o n kanra, lo fi n fi’bi han eda leemo
Eni ba w’aye (w’aye)
Eeyan to n gb’aye (gb’aye) E ma sai bikita p’aye kun fun ibi Olorun to da wa, ko da wa tori ibi Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Ti Oluwa ni ile, ati ekun re Ohun gbogbo to da s’oke eepe lo dara Satani lo so won d’ibi Eniyan e ma se ran lowo
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Ma je k’an f’ibi so e loruko, ire ni’wo je o ma gbagbe
Oruko a maa ro ni
Jowo ma se bi alaigbon Ohun t’aa ba n je la o da Ara e gb’oruko t’awon eeyan n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won) E gb’oruko t’eniyan n pe ‘ra re (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won) Oloriburuku, talaka n’on n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won)
Agan, were, alaarun ni won n pe ‘ra won (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won) Omugo, didinrin ni won n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won)
Alayebaje, atoole n’on n pe ‘ra won (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won)
Aletilapa ni won n p’omo won (oruko t’on n pe ‘ra won)
Ah e o mo p’ohun t’a ba pe loruko o lagbara lori eda Ohun ti o n la koja ooo, jowo ma fi pe ‘ra e mo Enikeni to ni ‘dojuko isese kan, e ma fi pe loruko Ma f’epe san epe, maa ko oruko buburu, satani lo n je baun
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
A ti d’ele aye na, dandan ni k’a laagun k’a to yo, sise pelu ero ire, wa a yo Awon elomiran a ni nile awon bi won o logun odun ni’gbeyawo won o ni le bimo
Won a ni nile won (won kii le ko’le)
Won a ni nile awon (won kii gbo k’on to ku) Idojuko won (n’on fi n pe ‘ra won) A ni aisan to n se ohun (n lo pa ‘ya ohun) Won a tun fun loruko (alaarun idile) Won a lohun gangan (logun ebi won) Eda n f’oruko isoro (p’oriki ara re) Won a ni b’o ti n se won (n’ile awon niyen)Eda e so’ro to dara jade, ero alaafia lOlorun ni si wa
Ma f’ogun enu se ‘ra e pa Pe ‘ra e ni hun to fe je Oruko to dara lOlorun so mi Oruko to logo o lEleda n pe mi Oruko to dara ni emi n je Aseda mo mi ire Emi ako’rewaye Emi agb’ayesayo Mi o ya’gan lona kankanAisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Igbagbo n se pupo loro eda (alaisan ti o ni ‘gbagbo ko le gba ‘wosan) Ireti logun f’oruko tuntun (alainireti ko le kuro loju kan) Eda segun nipa oro enu re (iku ati iye wa lori ahon) Ma s’ahon d’ida fi sa ara e si wewe (wa a jere ohun to ba f’enu so) Eni to da’na s’aaro ti o gbe ‘hun le’na (o daju ko ni ‘hun se)
O kan fe ya’na lasan ni, igbagbo ni yo ba ero e sise
Ja ijangbara fun oruko rere, oruko lo n ro ni Oruko to dara l’Olorun so mi Oruko to logo o l’Eleda n pe mi Oruko to dara ni emi n je
Aseda mo mi ire Emi ako’rewaye Emi agb’ayesayo Mi o ya’gan lona kankan Aisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Eda to n gbe ‘nu aye, yara pada s’odo Aseda
On lo mo’di oro, On lo le yanju e F’Adaniwaye se edidi aye re, mura lati s’atunse gbogbo Ko lati je oruko t’aye n so ni, to n ba ayanmo wo ‘jakadiOre b’Olorun d’owo po o, k’aye e ko le toro
Ore b’Olorun laja, ko le j’oruko tuntun Oruko to dara lOlorun so mi Oruko to logo o lEleda n pe mi Oruko to dara ni emi n je
Tope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Aseda mo mi ire Emi ako’rewaye Emi agb’ayesayo Mi o ya’gan lona kankan
Aisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Obedi-Edomu j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun) Bartholomew j’oruko tuntun (o je oruko tuntun) Jakobu j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun) Dafidi j’oruko tuntun (o je oruko tuntun)
Maria Magdaleni j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun) Soolu j’oruko tuntun (o je oruko tuntun) Peteru apeja j’oruko tuntun ooo (o j’oruko tuntun)
At’emi nipa eje odo aguntan, mo gba ire, to je ini mi pada
Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyanTope Alabi – Oruko Tuntun || Download Mp3 (Audio + Lyrics)
Emi t’a da (Emi t’a da) Laworan Olorun (Olorun) Emi eda (Emi eda) Mo ri ojurere (Ojurere) Mo loore ofe to ga julo Emi lori (Emi lori) Mi kii se iru o (Lailai) Emi t’a da (Emi t’a da) T’ewa t’ogo Olorun (Olorun)
Lat’odo Aseda o, ola mi o lakawe
A ti fi oruko tuntun pe mi, emi A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin A ti fi oruko tuntun pe mi, emi A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin A ti fi oruko tuntun pe mi, emi A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin .THE PREACHERS PORTAL
If you enjoy these daily readings and uploads by ThePreachersPortal Please Comment and share our articles on social media platforms. We have the mandate to spread the GOOD NEWS across the globe. A Mission To Spread The Gospel of Our Lord Jesus Christ through teachings, books, videos, audio, songs and more by the Inspiration of The Holy Spirit.